Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 15:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti ń gbé Àpótí Majẹmu OLUWA wọ ìlú Dafidi, Mikali ọmọbinrin Saulu yọjú láti ojú fèrèsé, ó rí Dafidi tí ń jó, tí ń fò sókè tayọ̀tayọ̀, ó sì pẹ̀gàn rẹ̀ ninu ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 15

Wo Kronika Kinni 15:29 ni o tọ