Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 15:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bá dáhùn pé, “Àwọn ọmọ Lefi nìkan ni wọ́n gbọdọ̀ ru Àpótí Majẹmu OLUWA, nítorí àwọn ni Ọlọrun yàn láti máa rù ú, ati láti máa ṣiṣẹ́ ìsìn rẹ̀ títí lae.”

Ka pipe ipin Kronika Kinni 15

Wo Kronika Kinni 15:2 ni o tọ