Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 14:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi ṣe akiyesi pé Ọlọrun ti fi ìdí ìjọba òun múlẹ̀ lórí Israẹli, ati pé Ọlọrun ti gbé ìjọba òun ga nítorí àwọn ọmọ Israẹli eniyan rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 14

Wo Kronika Kinni 14:2 ni o tọ