Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 12:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti inú àwọn ẹ̀yà tí wọ́n wà ní ìhà ìlà oòrùn Jọdani, ẹ̀yà Reubẹni, ti Gadi, ati ìdajì ti Manase, ọ̀kẹ́ mẹfa (120,000) ọmọ ogun tí wọ́n ní gbogbo ihamọra ogun ni wọ́n wá.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 12

Wo Kronika Kinni 12:37 ni o tọ