Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 12:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ẹ̀yà Gadi wọnyi ni olórí ogun, àwọn kan jẹ́ olórí ọgọrun-un ọmọ ogun, àwọn kan sì jẹ́ olórí ẹgbẹrun, olukuluku gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti jẹ́ akikanju sí.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 12

Wo Kronika Kinni 12:14 ni o tọ