Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 11:38-47 BIBELI MIMỌ (BM)

38. Joẹli, arakunrin Natani, ati Mibihari, ọmọ Hagiri,

39. Seleki, ará Amoni, ati Naharai, ará Beeroti, tí ń ru ihamọra Joabu ọmọ Seruaya.

40. Ira, ará Itiri, ati Garebu ará Itiri,

41. Uraya, ará Hiti, ati Sabadi, ọmọ Ahilai,

42. Adina, ọmọ Ṣisa, láti inú ẹ̀yà Reubẹni, olórí kan láàrin ẹ̀yà Reubẹni, pẹlu ọgbọ̀n àwọn ọmọ ogun rẹ̀;

43. Hanani, ọmọ Maaka, ati Joṣafati, ará Mitini;

44. Usaya, ará Aṣiteratu, Ṣama, ati Jeieli, àwọn ọmọ Hotamu, ará Aroeri,

45. Jediaeli, ọmọ Ṣimiri, ati Joha, arakunrin rẹ̀, ará Tisi,

46. Elieli, ará Mahafi, ati Jẹribai, ati Joṣafia, àwọn ọmọ Elinaamu, ati Itima ará Moabu;

47. Elieli, ati Obedi, ati Jaasieli, ará Mesoba.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 11