Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 1:34-36 BIBELI MIMỌ (BM)

34. Abrahamu ni baba Isaaki. Àwọn ọmọ Isaaki meji ni Esau ati Jakọbu.

35. Àwọn ọmọ Esau ni Elifasi, Reueli, ati Jeuṣi; Jalamu ati Kora.

36. Àwọn ọmọ Elifasi ni Temani, Omari ati Sefi; Gatamu, Kenasi, Timna ati Amaleki.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 1