Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 1:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Abrahamu ní obinrin kan tí ń jẹ́ Ketura. Ó bí àwọn ọmọ mẹfa wọnyi fún Abrahamu: Simirani, Jokiṣani ati Medani; Midiani, Iṣibaki ati Ṣua. Àwọn ọmọ ti Jokiṣani ni: Ṣeba ati Dedani.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 1

Wo Kronika Kinni 1:32 ni o tọ