Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 1:17-19 BIBELI MIMỌ (BM)

17. Ṣemu ni baba Elamu, Aṣuri, ati Apakiṣadi, Ludi, Aramu, ati Usi, Huli, Geteri ati Meṣeki.

18. Apakiṣadi ni baba Ṣela, Ṣela ni baba Eberi,

19. Eberi bí ọmọkunrin meji: Ekinni ń jẹ́ Pelegi, (nítorí pé ní àkókò tirẹ̀ ni àwọn eniyan ayé pín sí meji); ọmọ Eberi keji sì ń jẹ́ Jokitani,

Ka pipe ipin Kronika Kinni 1