Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 1:12-14 BIBELI MIMỌ (BM)

12. àwọn ará Patirusimu ati ti Kasilu tíí ṣe baba ńlá àwọn ará Filistia ati àwọn ará Kafito.

13. Àkọ́bí Kenaani ní Sidoni, lẹ́yìn rẹ̀ ó bí Heti,

14. Kenaani yìí náà ni baba ńlá àwọn ará Jebusi, àwọn ará Amori, ati àwọn ará Girigaṣi;

Ka pipe ipin Kronika Kinni 1