Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 1:1-4 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Adamu bí Seti, Seti bí Enọṣi.

2. Enọṣi bí Kenaani, Kenaani bí Mahalaleli, Mahalaleli bí Jaredi;

3. Jaredi bí Enọku, Enọku bí Metusela, Metusela bí Lamẹki;

4. Lamẹki bí Noa, Noa bí Ṣemu, Hamu, ati Jafẹti.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 1