Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Kinni 1:1-11 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Adamu bí Seti, Seti bí Enọṣi.

2. Enọṣi bí Kenaani, Kenaani bí Mahalaleli, Mahalaleli bí Jaredi;

3. Jaredi bí Enọku, Enọku bí Metusela, Metusela bí Lamẹki;

4. Lamẹki bí Noa, Noa bí Ṣemu, Hamu, ati Jafẹti.

5. Àwọn ọmọ Jafẹti ni Gomeri, Magogu, Madai, Jafani, Tubali, Meṣeki ati Tirasi.

6. Gomeri ni baba ńlá àwọn ọmọ Aṣikenasi, Difati ati Togama.

7. Jafani ni baba ńlá àwọn ọmọ Eliṣa, Taṣiṣi, ati àwọn ará Kitimu, ati Rodọni.

8. Hamu ni baba Kuṣi, Ijipti, Puti ati Kenaani,

9. Kuṣi bí Ṣeba, Hafila, Sabita, Raama ati Sabiteka; Raama ni baba Ṣeba ati Dedani,

10. Kuṣi bí Nimrodu. Nimrodu yìí ni ẹni kinni tí ó di akikanju ati alágbára lórí ilẹ̀ ayé.

11. Ijipti ni baba àwọn ará Lidia ati ti Anamu, ti Lehabu, ati ti Nafitu;

Ka pipe ipin Kronika Kinni 1