Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 9:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ògo ni fún OLUWA Ọlọrun rẹ, tí inú rẹ̀ dùn sí ọ, tí ó gbé ọ gorí oyè láti jọba ní orúkọ rẹ̀. Ó ní ìfẹ́ sí Israẹli, ó fẹ́ fi ìdí wọn múlẹ̀ títí lae; nítorí náà, ó fi ọ́ jọba lórí wọn, láti máa ṣe ìdájọ́ òtítọ́ ati òdodo.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 9

Wo Kronika Keji 9:8 ni o tọ