Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 8:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni mú iyawo rẹ̀, ọmọ Farao kúrò ní ìlú Dafidi, lọ sí ibi tí ó kọ́ fún un. Ó ní, “Iyawo mi kò gbọdọ̀ máa gbé ààfin Dafidi, ọba Israẹli; nítorí pé ibikíbi tí àpótí OLUWA bá ti wọ̀, ó ti di ibi mímọ́.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 8

Wo Kronika Keji 8:11 ni o tọ