Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 8:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ó gba Solomoni ní ogún ọdún láti kọ́ tẹmpili OLUWA ati ààfin tirẹ̀.

2. Lẹ́yìn náà, ó tún àwọn ìlú tí Huramu ọba, fún un kọ́, ó sì fi àwọn ọmọ Israẹli sibẹ.

3. Ó lọ gbógun ti ìlú Hamati ati Soba, ó sì ṣẹgun wọn.

Ka pipe ipin Kronika Keji 8