Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 6:5 BIBELI MIMỌ (BM)

‘Láti ìgbà tí mo ti mú àwọn eniyan jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti, n kò tíì yan ìlú kankan ninu ẹ̀yà Israẹli láti kọ́ ilé sí fún ìjọ́sìn ní orúkọ mi, bẹ́ẹ̀ ni n kò yan ẹnìkan kan láti jẹ́ olórí àwọn eniyan mi.

Ka pipe ipin Kronika Keji 6

Wo Kronika Keji 6:5 ni o tọ