Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 6:34 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí àwọn eniyan rẹ bá lọ sójú ogun, níbikíbi tí o bá rán wọn, láti lọ bá àwọn ọ̀tá wọn jà, tí wọ́n bá kọjú sí ìhà ìlú tí o ti yàn yìí ati sí ìhà ilé tí mo kọ́ fún ìjọ́sìn ní orúkọ rẹ yìí,

Ka pipe ipin Kronika Keji 6

Wo Kronika Keji 6:34 ni o tọ