Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 6:29 BIBELI MIMỌ (BM)

gbọ́ adura ati ẹ̀bẹ̀ ẹnìkọ̀ọ̀kan, tabi ti gbogbo Israẹli, eniyan rẹ, lẹ́yìn tí olukuluku ti mọ ìṣòro ati ìbànújẹ́ rẹ̀, bí wọ́n bá gbé ọwọ́ adura wọn sókè sí ìhà ilé yìí,

Ka pipe ipin Kronika Keji 6

Wo Kronika Keji 6:29 ni o tọ