Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 6:25 BIBELI MIMỌ (BM)

jọ̀wọ́ gbọ́ láti ọ̀run, kí o dárí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ọmọ Israẹli, eniyan rẹ, jì wọ́n, kí o sì mú wọn pada sórí ilẹ̀ tí o ti fún àwọn ati àwọn baba wọn.

Ka pipe ipin Kronika Keji 6

Wo Kronika Keji 6:25 ni o tọ