Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 6:10 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nisinsinyii OLUWA ti mú ìlérí rẹ̀ ṣẹ. Mo ti wà ní ipò baba mi, mo ti gorí ìtẹ́ ọba Israẹli, bí OLUWA ti ṣèlérí, mo sì ti kọ́ tẹmpili fún OLUWA Ọlọrun Israẹli.

Ka pipe ipin Kronika Keji 6

Wo Kronika Keji 6:10 ni o tọ