Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 4:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni ṣe ọ̀pá fìtílà wúrà mẹ́wàá bí àpẹẹrẹ tí wọ́n fún un. Ó gbé wọn kalẹ̀ ninu tẹmpili: marun-un ní ìhà gúsù, marun-un yòókù ní ìhà àríwá.

Ka pipe ipin Kronika Keji 4

Wo Kronika Keji 4:7 ni o tọ