Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 4:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó mọ àwọn ìkòkò, ó rọ ọkọ́ ati àmúga tí wọ́n fi ń mú ẹran, ati gbogbo ohun èlò wọn. Idẹ dídán ni Huramu fi ṣe gbogbo wọn fún Solomoni ọba, fún lílò ninu ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Kronika Keji 4

Wo Kronika Keji 4:16 ni o tọ