Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 4:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni ọba ṣe pẹpẹ idẹ kan tí ó gùn ní ogún igbọnwọ (mita 9), ìbú rẹ̀ náà sì jẹ́ ogún igbọnwọ (mita 9). Ó ga ní igbọnwọ mẹ́wàá (mita 4½).

Ka pipe ipin Kronika Keji 4

Wo Kronika Keji 4:1 ni o tọ