Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 36:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mẹẹdọgbọn ni Jehoiakimu nígbà tí ó jọba. Ó wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mọkanla. Ohun tí ó ṣe burú lójú OLUWA Ọlọrun rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 36

Wo Kronika Keji 36:5 ni o tọ