Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 36:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọdún yípo, Nebukadinesari, ọba Babiloni ranṣẹ lọ mú un wá sí Babiloni pẹlu àwọn ohun èlò olówó iyebíye tí ó wà ninu ilé OLUWA. Ó sì fi Sedekaya, arakunrin rẹ̀ jọba ní Jerusalẹmu ati Juda.

Ka pipe ipin Kronika Keji 36

Wo Kronika Keji 36:10 ni o tọ