Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 35:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olóyè náà fi tọkàntọkàn fún àwọn eniyan, ati àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi ní nǹkan. Hilikaya, Sakaraya ati Jehieli, àwọn alákòóso ninu ilé Ọlọrun, fún àwọn alufaa ní ẹgbẹtala (2,600) ọ̀dọ́ aguntan ati ọmọ ewúrẹ́ ati ọọdunrun (300) mààlúù fún ẹbọ Ìrékọjá.

Ka pipe ipin Kronika Keji 35

Wo Kronika Keji 35:8 ni o tọ