Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 35:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ dúró ní ibi mímọ́, kí ẹ sì pín ara yín sí ìsọ̀rí-ìsọ̀rí gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé àwọn arakunrin yín. Ìdílé kọ̀ọ̀kan gbọdọ̀ ní àwọn ọmọ Lefi tí wọn yóo wà pẹlu wọn.

Ka pipe ipin Kronika Keji 35

Wo Kronika Keji 35:5 ni o tọ