Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 34:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ìdájọ́ tí mo ti pinnu sórí Jerusalẹmu kò ní ṣẹlẹ̀ ní ìgbà ayé rẹ̀, ikú wọ́ọ́rọ́ ni yóo sì kú.”Àwọn eniyan náà bá pada lọ jíṣẹ́ fún ọba.

Ka pipe ipin Kronika Keji 34

Wo Kronika Keji 34:28 ni o tọ