Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 34:21 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ tọ Ọlọrun lọ fún èmi ati àwọn eniyan tí wọ́n kù ní Juda ati ní Israẹli, ẹ ṣe ìwádìí ohun tí a kọ sinu ìwé náà; nítorí pé àwọn baba ńlá wa tàpá sí ọ̀rọ̀ OLUWA, wọn kò sì ṣe ohun tí a kọ sinu ìwé yìí ni OLUWA ṣe bínú sí wa lọpọlọpọ.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 34

Wo Kronika Keji 34:21 ni o tọ