Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 34:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọba gbọ́ ohun tí ó wà ninu ìwé òfin náà, ó fa aṣọ rẹ̀ ya láti fi ìbẹ̀rù ati ìbànújẹ́ rẹ̀ hàn.

Ka pipe ipin Kronika Keji 34

Wo Kronika Keji 34:19 ni o tọ