Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 33:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Manase ṣi àwọn ará Juda ati Jerusalẹmu lọ́nà, tóbẹ́ẹ̀ tí wọ́n fi ṣe burúkú ju àwọn orílẹ̀-èdè tí OLUWA parun fún Israẹli lọ.

Ka pipe ipin Kronika Keji 33

Wo Kronika Keji 33:9 ni o tọ