Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 33:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tẹ́ pẹpẹ oriṣa sinu ilé OLUWA, ilé tí OLUWA ti sọ nípa rẹ̀ pé, “Ní Jerusalẹmu ni ibi ìjọ́sìn tí orúkọ mi yóo wà, tí ẹ óo ti máa sìn mí títí lae.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 33

Wo Kronika Keji 33:4 ni o tọ