Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 32:21 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá rán angẹli kan lọ pa gbogbo akọni ọmọ ogun, ati àwọn ọ̀gágun ati àwọn olórí ogun Asiria ní ibùdó wọn. Nítorí náà, pẹlu ìtìjú ńlá ni Senakeribu fi pada lọ sí ìlú rẹ̀. Nígbà tí ó wọ inú ilé oriṣa lọ, àwọn kan ninu àwọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin bá fi idà pa á.

Ka pipe ipin Kronika Keji 32

Wo Kronika Keji 32:21 ni o tọ