Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 32:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba Asiria yìí kọ àwọn ìwé àfojúdi kan sí OLUWA Ọlọrun Israẹli, ó ní, “Gẹ́gẹ́ bí àwọn oriṣa àwọn orílẹ̀-èdè yòókù kò ti lè gba àwọn eniyan wọn kúrò lọ́wọ́ mi, bẹ́ẹ̀ ni Ọlọrun Hesekaya náà kò ní lè gba àwọn eniyan rẹ̀ lọ́wọ́ mi.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 32

Wo Kronika Keji 32:17 ni o tọ