Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 31:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ohun tí ó ṣe ninu iṣẹ́ ìsìn ilé OLUWA, gẹ́gẹ́ bí òfin ati àṣẹ Ọlọ́run, ati wíwá tí ó wá ojurere Ọlọrun, gbogbo rẹ̀ ni ó ṣe tọkàntọkàn, ó sì dára fún un.

Ka pipe ipin Kronika Keji 31

Wo Kronika Keji 31:21 ni o tọ