Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 31:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kọ orúkọ àwọn alufaa ní ìdílé ìdílé, ṣugbọn àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n tó ẹni ogún ọdún sókè ni wọ́n kọ orúkọ wọn sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ipò wọn ati ìpín wọn.

Ka pipe ipin Kronika Keji 31

Wo Kronika Keji 31:17 ni o tọ