Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 31:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ṣolóòótọ́ ní kíkó àwọn ẹ̀bùn, ati ìdámẹ́wàá àwọn ohun ìyàsọ́tọ̀ náà pamọ́. Konanaya, ọmọ Lefi, ni olórí àwọn tí wọn ń bojútó wọn, Ṣimei, arakunrin rẹ̀ ni igbákejì rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 31

Wo Kronika Keji 31:12 ni o tọ