Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 30:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi dìde, wọ́n súre fún àwọn eniyan; OLUWA gbọ́ ohùn wọn, adura wọn sì gòkè lọ sí ibùgbé mímọ́ rẹ̀ lọ́run.

Ka pipe ipin Kronika Keji 30

Wo Kronika Keji 30:27 ni o tọ