Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 30:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n pa ọ̀dọ́ aguntan Àjọ Ìrékọjá ní ọjọ́ kẹrinla oṣù keji. Ojú ti àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi tí wọn kò tíì ya ara wọn sí mímọ́, tóbẹ́ẹ̀ tí wọ́n tètè lọ ya ara wọn sí mímọ́, tí wọ́n sì mú ẹbọ sísun wá sí ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Kronika Keji 30

Wo Kronika Keji 30:15 ni o tọ