Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó yọ́ ojúlówó wúrà bo gbogbo inú rẹ̀. Ó fi igi sipirẹsi tẹ́ gbogbo inú gbọ̀ngàn rẹ̀. Ó sì yọ́ wúrà dáradára bò ó lórí, ó ya igi ọ̀pẹ ati ẹ̀wọ̀n, ó fi dárà sórí rẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 3

Wo Kronika Keji 3:5 ni o tọ