Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 29:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Hesekaya jọba ní Juda nígbà tí ó di ẹni ọdún mẹẹdọgbọn; ó sì wà lórí oyè fún ọdún mọkandinlọgbọn. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Abija, ọmọ Sakaraya.

Ka pipe ipin Kronika Keji 29

Wo Kronika Keji 29:1 ni o tọ