Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 28:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Filistia ti gbógun ti àwọn ìlú tí ó wà ní ẹsẹ̀ òkè, ati ní agbègbè Nẹgẹbu, ní Juda. Wọ́n jagun gba Beti Ṣemeṣi, Aijaloni, ati Gederotu, wọ́n sì gba Soko, Timna, ati Gimso pẹlu àwọn ìletò ìgbèríko wọn, wọ́n bá ń gbé ibẹ̀.

Ka pipe ipin Kronika Keji 28

Wo Kronika Keji 28:18 ni o tọ