Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 26:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí Usaya di alágbára tán, ìgbéraga rẹ̀ tì í ṣubú. Ó ṣe aiṣootọ sí OLUWA Ọlọrun rẹ̀. Ó wọ inú tẹmpili OLUWA, ó lọ sun turari lórí pẹpẹ turari.

Ka pipe ipin Kronika Keji 26

Wo Kronika Keji 26:16 ni o tọ