Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 25:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn kò pa àwọn ọmọ wọn, gẹ́gẹ́ bí ìwé òfin Mose ti wí, níbi tí OLUWA ti pàṣẹ, pé, “A kò gbọdọ̀ pa baba nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ọmọ, tabi kí á pa ọmọ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ baba; olukuluku ni yóo kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ara rẹ̀.”

Ka pipe ipin Kronika Keji 25

Wo Kronika Keji 25:4 ni o tọ