Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 25:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, Jehoaṣi, ọba Israẹli, gòkè lọ, òun ati Amasaya ọba Juda sì kojú ara wọn lójú ogun ní Beti Ṣemeṣi ní ilẹ̀ Juda.

Ka pipe ipin Kronika Keji 25

Wo Kronika Keji 25:21 ni o tọ