Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 25:19 BIBELI MIMỌ (BM)

O bẹ̀rẹ̀ sí fọ́nnu pẹlu ìgbéraga pé o ti ṣẹgun àwọn ará Edomu, ṣugbọn, mo gbà ọ́ ní ìmọ̀ràn pé kí o dúró jẹ́ẹ́ sí ilé rẹ. Kí ló dé tí ò ń fi ọwọ́ ara rẹ fa ìjàngbọ̀n tí ó lè fa ìṣubú ìwọ ati àwọn eniyan rẹ?”

Ka pipe ipin Kronika Keji 25

Wo Kronika Keji 25:19 ni o tọ