Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 25:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú bí OLUWA sí Amasaya gan-an, ó sì rán wolii kan sí i kí ó sọ fún un pé, “Kí ló dé tí o fi ń bọ àwọn oriṣa tí kò lè gba àwọn eniyan rẹ̀ lọ́wọ́ rẹ?”

Ka pipe ipin Kronika Keji 25

Wo Kronika Keji 25:15 ni o tọ