Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 25:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ogun Israẹli tí Amasaya dá pada, tí kò jẹ́ kí wọ́n tẹ̀lé òun lọ sógun bá lọ, wọ́n kọlu àwọn ìlú Juda láti Samaria títí dé Beti Horoni. Wọ́n pa ẹgbẹẹdogun (3,000) eniyan, wọ́n sì kó ọpọlọpọ ìkógun.

Ka pipe ipin Kronika Keji 25

Wo Kronika Keji 25:13 ni o tọ