Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 25:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ọdún mẹẹdọgbọn ni Amasaya nígbà tí ó jọba; ó sì wà lórí oyè fún ọdún mọkandinlọgbọn ní Jerusalẹmu. Ìyá rẹ̀ ni Jehoadini ará Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Kronika Keji 25

Wo Kronika Keji 25:1 ni o tọ