Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kronika Keji 24:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn wọ́n dìtẹ̀ mọ́ ọn. Lẹ́yìn náà, ọba pàṣẹ pé kí wọn sọ ọ́ lókùúta pa ninu gbọ̀ngàn ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Kronika Keji 24

Wo Kronika Keji 24:21 ni o tọ